Punch News Today

Ẹ pàdé Owólabí Àjàsá tó n kó ipa olọ́pàá nínú awọn sinimá agbéléwò Yorùbá – Punch Newspapers

Ẹ pàdé Owólabí Àjàsá tó n kó ipa olọ́pàá nínú awọn sinimá agbéléwò YorùbáA bá ọ̀gbẹ́ni Owólabí Àjàsá sọ̀rọ̀ lórí ipa Ọlọ́pàá tó máa ń kó nínú àwọn eré sinimá àgbéléwò Yorùbá.

Ó ṣàlàyé pé bó tilẹ̀ jẹ́ pé òun kò ṣiṣẹ́ Ọlọ́pàá rí, àwọn ọ̀gágun Ọlọ́pàá máa ń kan sáárá sí i fún ipa Ọlọ́pàá tó ń kó nínú eré sinimá àgbéléwò Yorùbá nígbà gbogbo.

All rights reserved. This material, and other digital content on this website, may not be reproduced, published, broadcast, rewritten or redistributed in whole or in part without prior express written permission from PUNCH.

Contact: [email protected]Source link

Recent